Yoruba Hymn APA 193 - Tani le so t’ayo ti mbe

Yoruba Hymn APA 193 - Tani le so t’ayo ti mbe

 Yoruba Hymn  APA 193 - Tani le so t’ayo ti mbe

APA 193

1. Tani le so t’ayo ti mbe

 Ni agbala Paradise;

 Gbat’ amusua ba pada,

 T’o si di arole ogo ?


2. Ni ayo ni Baba fi wo,

 Eso ife Re ailopin;

 L’ayo l’ Omo wo ’le, t’o ri

 Ere iwaya-ija Re.


3. Tayotayo l’ Emi si nwo,

 Okan mimo t’ On so d’otun;

 Awon mimo at’ Angel nko

 Orin igbile Oba won. Amin.

Yoruba Hymn  APA 193 - Tani le so t’ayo ti mbe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 193 -  Tani le so t’ayo ti mbe . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post