Yoruba Hymn APA 229 - Jesu t’o ku, k’ o gb’ aiye la

Yoruba Hymn APA 229 - Jesu t’o ku, k’ o gb’ aiye la

Yoruba Hymn  APA 229 - Jesu t’o ku, k’ o gb’ aiye la

APA 229

 1. Jesu t’o ku, k’ o gb’ aiye la,

 Jinde kuro ninu oku,

 Nipa agbara Re;

 A da sile lowo iku,

 O d igbekun n’ igbekun lo,

 O ye, k’ o ma ku mo.


2. Enyin om’ Olorun, e wo

 Olugbala ninu ogo;

 O ti segun iku:

 Ma banuje, ma beru mo,

 O nlo pese aye fun nyin,

 Yio mu nyin lo ’le.


3. O f’ oju anu at’ ife

 Wo awon ti O ra pada;

 Awon ni ayo Re;

 O ri ayo at’ ise won,

 O bebe kin won le segun,

 Ki nwon ba joba lai. Amin.


Yoruba Hymn  APA 229 - Jesu t’o ku, k’ o gb’ aiye la


This is Yoruba Anglican hymns, APA 229- Jesu t’o ku, k’ o gb’ aiye la   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post