Yoruba Hymn APA 230 - B’ elese s’ owo po

Yoruba Hymn APA 230 - B’ elese s’ owo po

Yoruba Hymn  APA 230 - B’ elese s’ owo po

APA 230

 1. B’ elese s’ owo po,

 Ti nwon nde s’ Oluwa,

 Dimo si Kristi Re,

 Lati gan Oba na,

 B’ aiye sata,

 Pelu Esu,

 Eke ni nwon,

 Nwon nse lasan.


2. Olugbala joba!

 Lori oke Sion;

 Ase ti Oluwa

 Gbe Omo Tire ro:

 Lati boji

 O ni, k’ O nde,

 K’ O si goke,

 K’ O gba ni la.


3. F’ eru sin Oluwa,

 Si bowo f’ ase Re;

 F’ ayo wa sodo Re,

 F’ iwariri duro;

 E kunle fun,

 K’ e teriba;

 So t’ ipa Re,

 Ki Omo na. Amin.


Yoruba Hymn  APA 230 - B’ elese s’ owo po

This is Yoruba Anglican hymns, APA 230-   B’ elese s’ owo po  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post