Yoruba Hymn APA 231 - A mu ileri se

Yoruba Hymn APA 231 - A mu ileri se

Yoruba Hymn  APA 231 - A mu ileri se

APA 231

 1. A mu ileri se,

 Ise ’gbala pari:

 Oto at’ anu di ore,

 Om’ Olorun jinde.


2. Okan mi, yin Jesu,

 T’ O ru gbogbo’ ese re,

 T’ O ku f’ ese gbogbo aiye;

 O wa, k’ O ma ku mo.


3. Iku Re ra ’simi:

 Fun o, l’ O ji dide;

 Gbagbo, gba ekun ’dariji,

 T’ a sa l’ ami eje. Amin.


Yoruba Hymn  APA 231 - A mu ileri se


This is Yoruba Anglican hymns, APA 231-   A mu ileri se  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post