Yoruba Hymn APA 236 - Hossana si Oluwa wa

Yoruba Hymn APA 236 - Hossana si Oluwa wa

Yoruba Hymn  APA 236 - Hossana si Oluwa wa

APA 236

 1. Hossana si Oluwa wa!

 Hossana si Jesu Oba!

 Si Eleda, Olugbala,

 K’aiye, k’orun ko Hossana:

 Ko Hossana: “Hossana loke orun.”


2. Hossana l’orin Angeli,

 Hossana l’orin ti a ngbe;

 L’oke, nisale, yi wa ka,

 Oku at’ aye ngbe ’rin na :

 Ko Hossona: “Hossana loke orun.”


3. Olugbala ti ntoju wa,

 Pada wa ’le adura yi;

 A pejo ni oruko Re,

 Mu ileri Re se si wa:

 Ko Hossana: “Hossana loke orun.”


4. Sugbon, bori ohun gbogbo,

 Fi Emi Re kun okan wa,

 Ki okan wa je ibugbe

 Mimo ati yiye fun O:

 Ko Hossana: “Hossana loke orun.”


5. L’ojo k’ehin, ojo eru,

 T’aiye on orun o koja,

 Awon ti a ti rapada,

 Y’o tun gbe orin iyin na:

 Ko Hossana: “Hossana loke orun.” Amin.Yoruba Hymn  APA 236 - Hossana si Oluwa wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 236-  Hossana si Oluwa wa    . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post