Yoruba Hymn APA 235 - Ojo ’mole l’eyi

Yoruba Hymn APA 235 - Ojo ’mole l’eyi

Yoruba Hymn  APA 235 -   Ojo ’mole l’eyi

 APA 235

1. Ojo ’mole l’eyi:

 Ki ’mole wa l’oni

 ’Wo Orun, ran s’okunkun wa,

 K’ o si le oru lo.


2. Ojo ’simi l’eyi:

 S’ agbara wa d’otun;

 S’ori aibale aiya wa,

 Seri itura Re.


3. Ojo alafia:

 F’ Alafia fun wa;

 Da iyapa gbogbo duro,

 Si mu ija kuro.


4. Ojo adura ni:

 K’aiye sunmo Orun;

 Gbokan wa soke sodo Re,

 Si pade wa nihin.


5. Oba ojo l’eyi:

 Fun wa ni isoji;

 Ji oku okan wa s’ ife,

 ’Wo asegun iku. Amin.


 APA II


1. Kabo! ojo ’simi,

 T’o r’ ajinde Jesu;

 Ma bo wa m’okan yi soji,

 Si mu inu mi dun.


2. Oba tikare wa

 Bo Ijo Re loni;

 Nihinyi l’a wa t’a si ri

 A nyin, a ngbadura.


3. Ojo kan f’ adura

 N’nu ile mimo Re,

 O san j’egberun ojo lo

 T’a lo f’ adura ese.


4. Okan mi y’o f’ ayo

 Wa n’ iru ipo yi;

 Y’o si ma duro de ojo

 Ibukun ailopin. Amin.


Yoruba Hymn  APA 235 -   Ojo ’mole l’eyi


This is Yoruba Anglican hymns, APA 235 - Ojo ’mole l’eyi   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post