Yoruba Hymn APA 244 - Olorun goke lo

Yoruba Hymn APA 244 - Olorun goke lo

Yoruba Hymn  APA 244 - Olorun goke lo

APA 244

 1. Olorun goke lo

 Pelu ariwo nla;

 Awon ipe orun

 Nfi ayo Angel han;

 Gbogbo aiye yo, k e gberin,

 E f’ ogo fun Oba Ogo.


2. O j’ enia laiye,

 Oba wa ni loke;

 Ki gbogbo ile mo

 Ife nla Jesu wa;

 Gbogbo aiye, & c


3. Baba fi agbara

 Fun Jesu Oluwa;

 Ogun Angel mbo O,

 On l’ Oba nla orun;

 Gbogbo aiye, &c

 

4. L’ or’ ite Re mimo,

 O gb’ opa ododo;

 Gbogbo ota Re ni

 Yio ka lo bere.

 Gbogbo aiye, &c.


5. Ota Re l’ ota wa,

 Esu, aiye, ese;

 Sugbon y’o r’ ehin won,

 Ijoba Re y’o de.

 Gbogbo aiye, yo k’ e gberin,

 E f’ ogo fun Oba Ogo. Amin.


Yoruba Hymn  APA 244 - Olorun goke lo


This is Yoruba Anglican hymns, APA 244-  Olorun goke lo   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post