Yoruba Hymn APA 245 - Onigbagbo, e wa

Yoruba Hymn APA 245 - Onigbagbo, e wa

Yoruba Hymn  APA 245 - Onigbagbo, e wa

APA 245

 1. Onigbagbo, e wa,

 Israeli t’ emi:

 K’ a fi ayo pejo,

 K’ a gbohin didun yi;

 Jesu goke, O lo s’ orun,

 Alufa giga wa r’ orun.


2. Ojo etutu de,

 Israeli, e pe:

 A ti ru ebo tan,

 Ebo Odagutan;

 Jesu goke, &c.


3. Ibi mimo julo,

 L’ Olugbala wa lo,

 Pelu eje mimo

 T’ oju t’ ewure lo:

 Jesu goke, &c.


4. Kristian, e ho f’ ayo,

 Olorun gb’ ebo wa;

 Jesu mbebe pupo,

 Bi Alagbawi wa;

 Enikeni t’ o f’ ori fun,

 Y’o ni iye ainipekun. Amin.


Yoruba Hymn  APA 245 - Onigbagbo, e wa


This is Yoruba Anglican hymns, APA 244- Onigbagbo, e wa   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post