Yoruba Hymn APA 247 - Iwo ti goke lo

Yoruba Hymn APA 247 - Iwo ti goke lo

Yoruba Hymn  APA 247 -  Iwo ti goke lo

APA 247

 1. Iwo ti goke lo

 S’ile ayo orun,

 Lojojumo yite Re ka

 L’a ngbo orin iyin;

 Sugbon awa nduro,

 Labe eru ese;

 Jo ran Olutunu Re wa,

 K’o si mu wa lo ’le.


2. Iwo ti goke lo:

 Sugbon saju eyi,

 O koja ’rora kikoro,

 K’o to le de ade:

 Larin ibanuje,

 L’ao ma te siwaju;

 K’ona wa t’o kun f’omije,

 To wa si odo Re.


3. Iwo ti goke lo;

 Iwo o tun pada;

 Awon egbe mimo l’oke

 Ni y’o ba O pada

 Nipa agbara Re,

 K’a wa k’a ku n’nu Re,

 Gbat’a ba ji l’ojo ’dajo,

 Fi wa si otun Re. Amin.


Yoruba Hymn  APA 247 -  Iwo ti goke lo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 247-  Iwo ti goke lo    . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post