Yoruba Hymn APA 261 - A nsoro ile ’bukun ni

Yoruba Hymn APA 261 - A nsoro ile ’bukun ni

Yoruba Hymn  APA 261 - A nsoro ile ’bukun ni

APA 261

1. A nsoro ile ’bukun ni

 Ile didan at’ ile ewa;

 ’Gbagbogbo l’a nso t’ogo re;

 Y’o ti dun to lati de ’be!


2. A nsoro ita wura re,

 Oso odi re ti ko l’egbe;

 ’Faji re ko se f’enu so;

 Y’o ti dun to lati de ’be!


3. A nso p’ ese ko si nibe,

 Ko s’aniyan at’ ibanuje,

 Pelu ’danwo lode, ninu;

 Y’o ti dun to lati de ’be!


4. A nsoro orin iyin re,

 Ti a ko le f’orin aiye we;

 B’o ti wu k’orin wa dun to:

 Y’o ti dun to lati de ’be!


5. A nsoro isin ife re,

 Ti agbada t’ awon mimo nwo,

 Ijo akobi ti oke;

 Y’o ti dun to alti de ’be!


6. Jo, Oluwa, t’ibi t’ire,

 Sa se emi wa ye fun orun;

 Laipe, awa na yio mo,

 B’o ti dun to lati de ’be. Amin.Yoruba Hymn  APA 261 - A nsoro ile ’bukun ni

This is Yoruba Anglican hymns, APA 261- A nsoro ile ’bukun ni    . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post