Yoruba Hymn APA 276 - Baba wa orun, awa de

Yoruba Hymn APA 276 - Baba wa orun, awa de

Yoruba Hymn  APA 276 - Baba wa orun, awa de

APA 276

 1. Baba wa orun, awa de,

 Awa alailagbara;

 Fi Emi Mimo Re kun wa,

 K’ o so gbogbo wa d’ otun.

 Wa! Emi Mimo, jare wa!

 F’ ede titun s’ okan wa.

 Ebun nla Re ni l’ a ntoro,

 T’ ojo nla Pentikosti.


2. Ranti ileri Re, Jesu,

 Tu Emi Re s’ ara wa;

 Fi Alafia Re fun wa,

 T’ aiye ko le fifun ni.

 Wa! Emi Mimo, jare wa!

 Pa ese run l’ okan wa.

 Ebun nla Re ni l’ a ntoro,

 T’ ojo nla Pentikosti.


3. Adaba orun! ba le wa,

 Fi agbara Re fun wa;

 Ki gbogbo orile ede

 Teriba f’ Olugbala.

 K’ a gburo Re jakejado

 Ile okunkun wa yi.

 Ebun nla Re ni l’ a ntoro,

 T’ ojo nla Pentikosti. Amin.Yoruba Hymn  APA 276 - Baba wa orun, awa de

This is Yoruba Anglican hymns, APA 276-  Baba wa orun, awa de  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post