Yoruba Hymn APA 277 - Emi orun, gb’ adura wa

Yoruba Hymn APA 277 - Emi orun, gb’ adura wa

Yoruba Hymn  APA 277 - Emi orun, gb’ adura wa

APA 277

 1. Emi orun, gb’ adura wa,

 Wa gbe ‘nu ile yi;

 Sokale pel’ agbara Re,

 Wa, Emi Mimo, wa.


2. Wa, bi ‘mole; si fihan wa

 B’ aini wa tip o to:

 Wa, to wa si ona iye,

 Ti olododo nrin.


3. Wa, bi ina ebo mimo,

 S’ okan wa di mimo;

 Je ki okan wa je ore,

 F’ oruko Oluwa.


4. Wa bi iri, si wa bukun

 Akoko mimo yi:

 Ki okan alaileso wa

 Le yo l’ agbara Re.


5. Wa, bi adaba, n’ apa Re;

 Apa ife mimo;

 Wa, je ki Ijo Re l’ aiye,

 Dabi Ijo t’ orun.


6. Emi orun, gb’ adura wa,

 S’ aiye yi d’ ile Re;

 Sokale pel’ agbara Re,

 Wa, Emi Mimo, wa. Amin.


Yoruba Hymn  APA 277 - Emi orun, gb’ adura wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 277-  Emi orun, gb’ adura wa  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post