Yoruba Hymn APA 278 - Si O, Olutunu orun

Yoruba Hymn APA 278 - Si O, Olutunu orun

Yoruba Hymn  APA 278 - Si O, Olutunu orun

APA 278

 1. Si O, Olutunu orun,

 Fun ore at’ agbara Re,

 A nko Alleluya.


2. Si O, ife enit’ o wa

 Ninu majemu Olorun,

 A nko Alleluya.


3. Si O, Ohun Eniti npe

 Asako kuro n’nu ese,

 A nko Alleluya.


4. Si O, agbara Eniti

 O new ni mo, t’ o nwo ni san,

 A nko Alleluia.


5. Si O, ododo Eniti

 Gbogbo ’leri Re je tiwa,

 A nko Alleluia.


6. Si O, Oluko at’ Ore,

 Amona wa toto d’ opin,

 A nko Alleluya.


7. Si O, Eniti Kristi ran,

 Ade on gbongbo ebun Re,

 A nko Alleluia.


8. Si O, Enit’ o je okan

 Pelu Baba ati Omo,

 A nko Alleluya. Amin.Yoruba Hymn  APA 278 - Si O, Olutunu orun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 278 -  Si O, Olutunu orun . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post