Yoruba Hymn APA 296 - Bibel’ iwe aiyeraiye

Yoruba Hymn APA 296 - Bibel’ iwe aiyeraiye

 Yoruba Hymn  APA 296 - Bibel’ iwe aiyeraiye

APA 296

1. Bibel’ iwe aiyeraiye!

 Tani le r’ idi re?

 Tani le so idide re?

 Tani le m’ opin re?


2. Asiri Olodumare;

 Iko Oba orun;

 Ida t’o pa oro iku;

 Aworan Olorun.


3. Okan ni O larin opo

 Iwe aiye ’gbani,

 Iwo l’o s’ ona igbala

 Di mimo f’ araiye.


4. Isura ti Metalokan,

 Oba nla t’o gunwa;

 Jo, tumo ara re fun mi,

 Ki ’m ye siyemeji.


5. Ki ’m’ si o pelu adura,

 Ki ’m’ k’ eko ninu re;

 Iwo Iwe Aiyeraiye

 F’ ife Jesu han mi. Amin.Yoruba Hymn  APA 296 - Bibel’ iwe aiyeraiye

This is Yoruba Anglican hymns, APA 296-  Bibel’ iwe aiyeraiye  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post