Yoruba Hymn APA 297 - Tori Mi at’ Ihinrere

Yoruba Hymn APA 297 - Tori Mi at’ Ihinrere

Yoruba Hymn  APA 297 - Tori Mi at’ Ihinrere

APA 297

 1. “Tori Mi at’ Ihinrere,

 E lo so t’ Irapada;

 Awon onse Re nke, ‘Amin’ !

 Tire ni gbogbo ogo;

 Nwon snso tibi, tiya, t’iku,

 Ife etutu nla Re;

 Nwon ka ohun aiye s’ ofo,

 T’ajinde on ‘joba Re.


2. Gbo, gbo ipe ti jubili,

 O ndun yi gbogb’aiye ka;

 N’ile ati loju okun,

 A ntaqn ihin igbala,

 Bi ojo na ti nsunmole,

 T’ Ogun si ngbona janjan,

 Imole Ila – orun na

 Y’o mo larin okunkun.


3. Siwaju ati siwaju

 Lao ma gbo Halleluya,

 Ijo ajagun y’o ma yo,

 Pel’ awon oku mimo;

 A fo aso won n’nu eje,

 Duru wura won sin dun;

 Aiye at’orun d’ohun po,

 Nwon nko orin isegun.


4. O de, Enit’ a nw’ona Re,

 Eni ikehin na de,

 Immanueli to d’ade,

 Oluwa awon mimo,

 Iye, Imole at’ Ife,

 Metalokan titi lai;

 Tire ni Ite Olorun

 Ati t’ Odo-agutan. Amin.Yoruba Hymn  APA 297 - Tori Mi at’ Ihinrere

This is Yoruba Anglican hymns, APA 297- Tori Mi at’ Ihinrere  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post