Yoruba Hymn APA 298 - Ma gbadura; Emi mbebe n’nu re

Yoruba Hymn APA 298 - Ma gbadura; Emi mbebe n’nu re

Yoruba Hymn  APA 298 - Ma gbadura; Emi mbebe n’nu re

APA 298

1. Ma gbadura; Emi mbebe n’nu re

 Fun gbogbo aini re igbagbogbo.


2. Ma gbadura; labe eru ese,

 Adura nri eje Jesu tin san


3. Ma gbadura; b’are tile mu o

 Adura ngbe wa s’eba ‘te Baba


4. Ma gbadura; n’nu wahala aiye,

 Adura l’o nfun okan n’ isimi.


5. Ma gbadura; b’ ayo ba yi o ka,

 Adura nlu harp, o nkorin angel’


6. Ma gbadura; b’ awon t’ o feran ku,

 Adura mba won mu omi iye.


7. Gbogb’ ohun aiye y’o b’aiye koja

 Adura wa titi: ma gbadura. Amin. 



Yoruba Hymn  APA 298 - Ma gbadura; Emi mbebe n’nu re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 298- Ma gbadura; Emi mbebe n’nu re . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post