Yoruba Hymn APA 299 - Ninu gbogbo iji ti nja

Yoruba Hymn APA 299 - Ninu gbogbo iji ti nja

Yoruba Hymn  APA 299 - Ninu gbogbo iji ti nja

APA 299

 1. Ninu gbogbo iji ti nja,

 Ninu gbogbo igbi ‘ponju,

 Abo kan mbe, ti o daju;

 O wa labe ite-anu.


2. Ibi kan wa ti Jesu nada

 Ororo ayo s’ ori wa;

 O dun ju ibi gbogbo lo;

 Ite-anu t’ a f’eje won.


3. Ibi kan wa fun idapo,

 Nibi ore npade ore;

 Lairi ‘ra, nipa igbagbo,

 Nwon y’ ite-anu kanna ka.


4. A! nibo ni a bas a si,

 Nigba ‘danwo at’ iponju?

 A ba se le bori Esu,

 Bosepe ko si ‘te-anu?


5. A! bi idi l’a fo sibe,

 B’enipe aiye ko si mo,

 Orun wa ‘pade okan wa,

 Ogo sib o ite-anu. Amin.
Yoruba Hymn  APA 299 - Ninu gbogbo iji ti nja

This is Yoruba Anglican hymns, APA 299-  Ninu gbogbo iji ti nja  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post