Yoruba Hymn APA 300 - Lo, l’ oro kutukutu

Yoruba Hymn APA 300 - Lo, l’ oro kutukutu

Yoruba Hymn  APA 300 - Lo, l’ oro kutukutu

APA 300

 1. Lo, l’ oro kutukutu,

 Lo, ni osangangan,

 Lo, ni igba asale,

 Lo, ni oganjo or;

 Lo’ t’ iwo t’ inu rere

 Gbagbe ohun aiye,

 Si kunle n’ iyewu re,

 Gbadura nikoko,


2. Ranti awon t’ o fe o,

 At’ awon t’ iwo fe;

 Awon t’ o korira re,

 Si gbadura fun won;

 Lehin na, toro ’bukun,

 Fun ’wo tikalare;

 Ninu adura re, ma

 Pe oruko Jesu.


3. B’ aye ati gbadura

 Nikoko ko si si,

 T’ okan re fe gbadura,

 ’Gbat’ ore yi o ka,

 ’Gbana, adura jeje

 Lat’ inu okan re

 Y’o de odo Olorun,

 Olorun alanu.

 

4. Ko si ayo kan l’ aiye,

 T’ o si ju eyi lo;

Nit’ agbara t’ a fun wa,

Lati ma gbadura;

’Gbat’ inu re ko ba dun,

Je k’ okan re wole;

Ninu ayo re gbogbo,

Ranti or’ofe re. Amin.Yoruba Hymn  APA 300 - Lo, l’ oro kutukutu

This is Yoruba Anglican hymns, APA 300-  Lo, l’ oro kutukutu. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post