Yoruba Hymn APA 301 - Oju kan mbe ti ki togbe

Yoruba Hymn APA 301 - Oju kan mbe ti ki togbe

 Yoruba Hymn  APA 301 - Oju kan mbe ti ki togbe

APA 301

1. Oju kan mbe ti ki togbe,

 Nigbat’ ile bas u;

 Eti kan si mbe ti ki ise,

 ‘Gbati orun ba wo.


2. Apa kan mbe, ti ko le re,

 ‘Gba ‘pa enia pin;

 Ife kan mbe, ti ko le ku,

 ‘Gba ‘fe aiye ba ku.


3. Oju na wno awon Seraf,

 Apa na d’ orun mu;

 Eti na kun f’ orin Angel,

 Ife na ga loke.


4. Ipa kan l’ enia le lo,

 ‘Gbat’ ipa gbogbo pin;

 Lati ri oju at’ apa,

 Ati ife nla na.


5. Ipa na ni adura wa,

 Ti nlo ‘waju ite;

 T’o nmi owo t’o s’aiye ro,

 Lati mu gbala wa.


6. Iwo t’anu Re ko lopin,

 T’ife Re ko le ku;

 Je k’a n’ igbagbo at’ ife,

 K’a le ma gbadura. Amin.



Yoruba Hymn  APA 301 - Oju kan mbe ti ki togbe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 301-  Oju kan mbe ti ki togbe   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post