Yoruba Hymn APA 347 - Wo! b’ o ti dun to lati ri

Yoruba Hymn APA 347 - Wo! b’ o ti dun to lati ri

 Yoruba Hymn  APA 347 - Wo! b’ o ti dun to lati ri

APA 347

1. Wo! b’ o ti dun to lati ri

 Awon ara t’ o re;

 Ara ti okan won s’ okan,

 L’ egbe ide mimo.

 

2. ’Gba isan ’fe t’ odo Krist sun,

 O san s’ okan gbogbo;

 Alafia Olodumare

 Dabobo gbogbo re.


3. O dabi ororo didun,

 Ni irugbon Aaron;

 Kikan re m’ aso re run ’re,

 O san s’ agbada re.


4. O dara b’ iri owuro,

 T’ o nse soke Sion,

 Nibi t’ Olorun f’ ogo han,

 T’ o m’ ore-ofe han. Amin.



Yoruba Hymn  APA 347 - Wo! b’ o ti dun to lati ri

This is Yoruba Anglican hymns, APA 347- Wo! b’ o ti dun to lati ri. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post