Yoruba Hymn APA 348 - Alafia ni f’ okan na

Yoruba Hymn APA 348 - Alafia ni f’ okan na

Yoruba Hymn  APA 348 - Alafia ni f’ okan na

APA 348

 1. Alafia ni f’ okan na,

 Nibit’ ife gbe wa;

 Ife ni o tobi julo

 Ninu gbogbo ebun.


2. Asan ni gbogbo ’gbagbo je,

 Asan ni ’beru wa;

 Ese y’o bori okan wa,

 B’ ife ko si nibe.


3. Ife nikan ni y’o r’ opin

 Igbagbo on ’reti;

 Nipa re l’ a o ma korin,

 Loke orun lohun. Amin.Yoruba Hymn  APA 348 - Alafia ni f’ okan na

This is Yoruba Anglican hymns, APA 348- Alafia ni f’ okan na  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post