Yoruba Hymn APA 369 - Ese d’ eru? wo, Jesu ni

Yoruba Hymn APA 369 - Ese d’ eru? wo, Jesu ni

Yoruba Hymn  APA 369 - Ese d’ eru? wo, Jesu ni

APA 369

 1. Ese d’ eru? wo, Jesu ni!

 On tikare l’ o ntoko;

 E ta ’gbokun si afefe,

 Ti y’o gbe wa la ibu,

 Lo si ilu

 ’Bit’ olofo ye sokun.


2. B’a ko mo ’bit’ a nlo gun si,

 Ju b’a ti ngbohin re lo;

 Sugb’a ko ’hun gbogbo sile,

 A tele ihin t’a gbo;

 Pelu Jesu,

 A nla arin ibu lo.


3. A ko beru igbi okun;

 A ko si ka iji si;

 Larin ’rukerudo, a mo

 P’ Oluwa mbe nitosi;

 Okun gba gbo,

 Iji sa niwaju Re.


4. B’ ayo wa o ti to lohun,

 Iji ki ja de ibe:

 Nibe l’ awon ti nsota wa

 Ko le yow a lenu mo:

 Wahala pin

 L’ ebute alafia na. Amin.




Yoruba Hymn  APA 369 - Ese d’ eru? wo, Jesu ni

This is Yoruba Anglican hymns, APA 369- Ese d’ eru? wo, Jesu ni  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post