Yoruba Hymn APA 375 - Ha! Egbe mi, e w’ asia

Yoruba Hymn APA 375 - Ha! Egbe mi, e w’ asia

Yoruba Hymn  APA 375 - Ha! Egbe mi, e w’ asia

APA 375

 1. Ha! Egbe mi, e w’ asia

 Bi ti nfe lele!

 Ogun Jesu fere de na,

 A fere gun!

 D’ odi mu, emi fere de,”

 Beni Jesu nwi,

 Ran ‘dahun pada s’ orun , pe,

 Awa o dimu.


2. Wo opo ogun ti mbo wa,

 Esu nko won bo;

 Awon alagbara nsubu,

 A fe damu tan!

 D’ odi mu, &c.

 

3. Wo asia Jesu ti nfe;

 Gbo ohun ipe;

 A o segun gbogbo ota

 Ni oruko Re.

 D’ odi mu, &c.


4. Ogun ngbona girigiri,

 Iranwo w ambo;

 Balogun wa mbo wa tete,

 Egbe, tujuka!

 D’ odi mu, &c. Amin.Yoruba Hymn  APA 375 - Ha! Egbe mi, e w’ asia

This is Yoruba Anglican hymns, APA 375- Ha! Egbe mi, e w’ asia  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post