Yoruba Hymn APA 376 - A ko ni ’bugbe kan nihin

Yoruba Hymn APA 376 - A ko ni ’bugbe kan nihin

Yoruba Hymn  APA 376 - A ko ni ’bugbe kan nihin

APA 376

 1. A ko ni ’bugbe kan nihin;

 Eyi ba elese n’nu je;

 Ko ye k’ enia mimo kanu,

 Tori nwon nfe simi t’ orun.


2. A ko ni ’bugbe kan nihin,

 O buru b’ ihin je ’le wa;

 K’ iro yi mu inu wa dun,

 Awa nwa ilu nla t’ o mbo.


3. A ko ni ’bugbe kan nihin,

 A nwa ilu nla t’ a ko ri;

 Sion ilu Oluwa wa,

 O ntan imole titi lai.


4. Iwo ti nse ’bugbe ife,

 Ibiti ero gbe nsimi;

 Emi ba n’ iye b’ adaba,

 Mba fo sinu re, mba simi.


5. Dake okan mi, ma binu,

 Akoko Oluwa l’ o ye;

 T’ emi ni lati se ’fe Re,

 Tire, lati se mi l’ ogo. Amin.



Yoruba Hymn  APA 376 - A ko ni ’bugbe kan nihin

This is Yoruba Anglican hymns, APA 376- A ko ni ’bugbe kan nihin. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post