Yoruba Hymn APA 377 - Duro, duro fun Jesu

Yoruba Hymn APA 377 - Duro, duro fun Jesu

Yoruba Hymn  APA 377 - Duro, duro fun Jesu

APA 377

 1. Duro, duro fun Jesu,

 Enyin om’ogun Krist:

 Gbe asia Re soke,

 A ko gbodo fe ku;

 Lat’ isegun de ‘segun

 Ni y’o to ogun Re:

 Tit’ ao segun gbogb’ ota,

 Ti Krist y’o j’ Oluwa.


2. Duro, duro fun Jesu;

 F’eti s’ohun ipe;

 Jade lo s’oju ‘ija,

 L’oni ojo nla Re:

 Enyin akin ti nja fun,

 Larin ainiye ota,

 N’nu ewu, e ni ‘gboiya;

 E kojuja s’ota.


3. Duro, duro fun Jesu;

 Duro, l’agbara Re;

 Ipa enia ko to,

 Ma gbekele tire:

 Di ‘hamora ‘hinrere,

 Ma sona, ma gbadura,

 B’ise tab’ ewu ba pe,

 Ma se alai de ‘be.


4. Duro, duro fun Jesu,

 Ija na ki y’o pe;

 Oni, ariwo ogun,

 Ola, orin ‘segun:

 Eni t’o ba si segun,

 Y’o gba ade iye:

 Y’o ma ba Oba Ogo

 Joba titi lailai. Amin.



Yoruba Hymn  APA 377 - Duro, duro fun Jesu

This is Yoruba Anglican hymns, APA 377- Duro, duro fun Jesu  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post