Yoruba Hymn APA 378 - Omogun Krist, dide

Yoruba Hymn APA 378 - Omogun Krist, dide

Yoruba Hymn  APA 378 - Omogun Krist, dide

APA 378

 1. Omogun Krist, dide,

 Mu hamora nyin wo:

 Mu ’pa t’ Olorun fi fun nyin,

 Nipa ti Omo Re.


2. Gbe ’pa Olorun wo,

 T’ Oluwa omogun;

 Enit’ o gbekele Jesu,

 O ju asegun lo.


3. Ninu ipa re nla,

 On ni ki e duro;

 ’Tori k’ e ba le jija na,

 E di hamora nyin.


4. Lo lat’ ipa de ’pa,

 Ma ja, ma gbadura;

 Te agbara okunkun ba,

 E ja k’ e si segun.


5. Lehin ohun gbogbo,

 Lehin gbogbo ija,

 K’ e le segun n’ipa Kristi,

 K’ e si duro sinsin. Amin.Yoruba Hymn  APA 378 - Omogun Krist, dide

This is Yoruba Anglican hymns, APA 378- Omogun Krist, dide  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post