Yoruba Hymn APA 379 - Omo Olorun nlo s’ ogun

Yoruba Hymn APA 379 - Omo Olorun nlo s’ ogun

Yoruba Hymn  APA 379 - Omo Olorun nlo s’ ogun

APA 379

 1. Omo Olorun nlo s’ ogun,

 Lati gb’ ade Oba:

 Opagun Re si nfe lele,

 Tal’ o s’ omogun Re?


2. Enit o le mu ago na,

 T’ o le bori ’rora,

 T’ o le gbe agbelebu Re,

 On ni Omogun Re.


3. Martir ikini t’ o ko ku,

 T’ o r’ orun si sile;

 T’o ri Oluwa re loke,

 T’ o pe, k’o gba on la.


4. T’ on ti ’dariji l’enu,

 Ninu ’rora iku,

 O bebe f’ awon t’ o npa lo:

 Tani le se bi re?


5. Egbe mimo; awon wonni

 T’Emi Mimo ba le;

 Awon akoni mejila,

 Ti ko ka iku si:


6. Nwon f’aiya ran ida ota,

 Nwon ba eranko ja;

 Nwon f’orun won lele fun ku,

 Tani le se bi won?


7. Egbe ogun, t’ agba, t’ ewe,

 T’okunrin t’obinrin;

 Nwon y’ite Olugbala ka,

 Nwon wo aso funfun.


8. Nwon de oke orun giga,

 N’nu ’se at’ iponju:

 Olorun fun wa l’ agbara

 K’ a le se bi won. Amin.Yoruba Hymn  APA 379 - Omo Olorun nlo s’ ogun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 379- Omo Olorun nlo s’ ogun  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post