Yoruba Hymn APA 381 - Ninu oru ibanuje

Yoruba Hymn APA 381 - Ninu oru ibanuje

Yoruba Hymn  APA 381- Ninu oru ibanuje

APA 381

 1. Ninu oru ibanuje

 L’ awon egbe ero nrin;

 Nwon nkorin ’reti at’ ayo,

 Nwon nlo sile ileri.


2. Niwaju wa nin’ okunkun,

 Ni imole didan ntan;

 Awon arakonrin nsate,

 Nwon nrin lo li aifoya.


3. Okan ni imole orun,

 Ti ntan s’ ara enia Re;

 Ti nle gbogbo eru jina,

 Ti ntan yi ona wa ka.


4. Okan ni iro ajo wa,

 Okan ni igbagbo wa;

 Okan l’ eni t’ a gbekele,

 Okan ni ireti wa.


5. Okan l’ orin t’ egberun nko,

 Bi lati okan kan wa;

 Okan n’ ija, okan l’ ewu,

 Okan ni irin orun.


6. Okan ni inu didun wa,

 L’ ebute ainipekun;

 Nibiti Baba wa orun,

 Y’o ma joba titi lai.


7. Nje k’ a ma nso, arakonrin,

 T’ awa ti agbelebu:

 E je k’ a ru, k’ a si jiya,

 Tit’ a o fi ri ’simi.


8. Ajinde nla fere de na,

 Boji fere si sile;

 Gbogbo okun y’o si tuka,

 Gbogbo lala y’ o si tan. Amin.



Yoruba Hymn  APA 381 - Ninu oru ibanuje

This is Yoruba Anglican hymns, APA 381- Ninu oru ibanuje. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post