Yoruba Hymn APA 382 - Iranse Oluwa

Yoruba Hymn APA 382 - Iranse Oluwa

Yoruba Hymn  APA 382 - Iranse Oluwa

APA 382

 1. Iranse Oluwa!

 E duro nid’ ise;

 E toju oro mimo Re,

 E ma sona Re sa.


2. Je k’ imole nyin tan,

 E tun fitila se;

 E damure girigiri,

 Oruko Re l’ eru.


3. Sora! l’ ase Jesu,

 B’a tin so, ko jina;

 B’o ba kuku ti kan ’lekun,

 Ki e si fun logan.


4. Iranse ’re l’ eni

 Ti a ba nipo yi;

 Ayo l’ on o fi r’ Oluwa,

 Y’o f’ ola de l’ ade.


5. Kristi tikalare

 Y’o te tabili fun,

 Y’o gb’ ori iranse nag a

 Larin egbe Angel. Amin.Yoruba Hymn  APA 382 - Iranse Oluwa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 382-  Iranse Oluwa . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post