Yoruba Hymn APA 398 - Emi at’ ara ile mi

Yoruba Hymn APA 398 - Emi at’ ara ile mi

Yoruba Hymn  APA 398 - Emi at’ ara ile mi

APA 398

 1. Emi at’ ara ile mi,

 Yio ma sin Oluwa wa;

 Sugbon emi papa;

 Yio f’ iwa at’ oro han,

 Pe mo mo Oluwa t’ orun,

 Mo nfokan toto sin.


2. Em’ o f’ apere ’re le ’le;

 Ngo mu idena na kuro;

 Lodo om’ odo mi;

 Ngo f’ ise won han n’ iwa mi,

 Sibe n’nu ’se mi ki nsi ni

 Ola na ti ife.


3. Emi ki y’o soro gb’ ipe,

 Emi ki y’o pe tu ninu,

 Om’ ehin Olorun;

 Mo si fe je eni mimo,

 Ki nsi fa gbogbo ile mi,

 S’oju ona orun.


4. Jesu, b’O ba da ’na ’fe na,

 Ohun elo t’ Iwo fe lo,

 Gba s’ owo ara Re!

 Sise ife rere n’nu mi,

 Ki nfi b’ onigbagbo toto

 Ti ngbe l’ aiye han won.


5. Fun mi l’ ore-ofe toto,

 Nje! Emi de lati jeri

 ’Yanu oruko Re,

 Ti o gba mi l’owo egbe;

 Ire eyi t’a mo l’ okan,

 Ti gbogb’ ahon le so.


6. Emi t’o bo lowo ese,

 Mo wa lati gba ’le mi la,

 Ki nwasu ’dariji;

 F’omo, f’aya, f’ omo-do mi,

 Lati mu won to ’na rere

 Lo si orun mimo. Amin.Yoruba Hymn  APA 398 - Emi at’ ara ile mi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 398-  Emi at’ ara ile mi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post