Yoruba Hymn APA 409 - Loni ni Jesu pe

Yoruba Hymn APA 409 - Loni ni Jesu pe

Yoruba Hymn  APA 409 - Loni ni Jesu pe

APA 409

 1. Loni ni Jesu pe !

 Asako, wa;

 A! okan okunkun,

 Ma kiri mo.


2. Loni ni Jesu pe!

 Tetilele;

 Wole fun Jesu, ni

 ’Le owo yi.


3. Loni ni Jesu pe!

 Sa asala;

 Iji igbesan mbo,

 Iparun mbo.


4. Loni ni Emi pe!

 Jowo ’ra re;

 Ma mu k’o binu lo,

 Sa anu ni. Amin.Yoruba Hymn  APA 409 - Loni ni Jesu pe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 409- Loni ni Jesu pe . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post