Yoruba Hymn APA 418 - Awa f’ ori bale fun | O Jesu

Yoruba Hymn APA 418 - Awa f’ ori bale fun | O Jesu

Yoruba Hymn  APA 418 - Awa f’ ori bale fun | O Jesu

APA 418

 1. Awa f’ ori bale fun | O Jesu,

 ’Wo ti s’ Olori Ijo awon | enia Re,

 Ijo ti mbe laiye yi, ati lo| run pelu:

 Alle| luya!


2. ’Wo t’o ku, t’o si jin| de fun wa,

 T’o mbe lodo Baba bi Ala| gbawi wa,

 K’ ogo at’ olanla | je Tire:

 Alle| luya!


3. Ati li ojo nla Pen| tikosti,

 Ti o ran Parakliti | si aiye

 Olutunu nla Re ti mba wa gbe:

 Alle| luya!


4. Lat’ ori ite Re l’ o| ke orun,

 L’O si nwo gbogbo awon o| jise Re,

 T’O si nsike gbogbo awon Aje| riku Re:

 Alle| luya!


5. A fi iyin at’ olanla f’ o| ruko Re,

 N’tori iku gbogbo awon o| jise Re,

 Ni gbogbo ile Yo| ruba yi:

 Alle| luya! Amin.Yoruba Hymn  APA 418 - Awa f’ ori bale fun | O Jesu

This is Yoruba Anglican hymns, APA 418- Awa f’ ori bale fun | O Jesu . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post