Yoruba Hymn APA 429 - Wo orison ohun rere

Yoruba Hymn APA 429 - Wo orison ohun rere

 Yoruba Hymn  APA 429 - Wo orison ohun rere

APA 429

1. ‘Wo orison ohun rere

 Awa fe se ‘fe re;

 Ohun wo l’ a le fi fun O,

 Oba gbogbo aiye?


2. L’ aiye yi, ‘Wo ni otosi,

 T’ o je enia Re:

 Oruko won n’ Iwo njewo

 Niwaju Baba Re.


3. ‘Gba nwon ba nke n’ inira won,

 Ohun Re l’ awa ngbo;

 ‘Gba ba si nse itoju won,

 Awa nse ‘toju Re.


4. Jesu, ma sai gba ore wa,

 Si f’ ibukun Re si;

 Ma f’ ibukun Re s’ ebun wa,

 Fun awon t’ a nfi fun.


5. Fun Baba, Omo at’ Emi,

 Olorun ti a nsin;

 Ni ki a ma fi ogo fun,

 Titi aiyeraiye. Amin.Yoruba Hymn  APA 429 - Wo orison ohun rere

This is Yoruba Anglican hymns, APA 429- Olori Ijo t’ orun . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post