Yoruba Hymn APA 432 - Gege bi oro ore Re

Yoruba Hymn APA 432 - Gege bi oro ore Re

Yoruba Hymn  APA 432 - Gege bi oro ore Re

APA 432

 1. Gege bi oro ore Re,

 Ninu irele nla,

 Emi o se yi Olua,

 Emi o ranti Re.


2. Ara Re ti a bu fun mi,

 Yio je onje mi;

 Mo gba ago majemu Re,

 Lati se ranti Re.


3. Mo le gbagbe Getsemane,

 Ti mo r’ ijamu Re,

 Iya on ogun eje Re,

 Ki nma sir anti Re?


4. Ngo ranti gbogbo ‘rora Re,

 At’ ife Re si mi;

 Bi o ku emi kan fun mi,

 Emi o ranti Re.


5. ‘Gbati enu mi ba pamo,

 Ti iye mi bar a,

 Ti O ba de n’ ijoba Re.

 Jesu, jo ranti mi. Amin.



Yoruba Hymn  APA 432 - Gege bi oro ore Re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 432 - Gege bi oro ore Re. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post