Yoruba Hymn APA 466 - Gbat’ O ba de, gbat’ O ba de

Yoruba Hymn APA 466 - Gbat’ O ba de, gbat’ O ba de

Yoruba Hymn  APA 466 - Gbat’ O ba de, gbat’ O ba de

APA 466

 1. Gbat’ O ba de, gbat’ O ba de,

 Lati sir’ oso Re;

 Gbogbo’ oso Re iyebiye,

 Awon ti O fe!

Bi irawo owuro, nwon ns’ ade Re loso,

 Ewa won o yo pupo, ewa f’ ade Re.


2. Yio kojo, yio kojo,

 Oso ijoba Re;

 Awon mimo, awon didan,

 Awon it O fe.

Bi irawo owuro, nwon ns’ ade Re loso,

 Ewa won o yo pupo, ewa f’ ade Re.


3. Awon ewe, awon ewe

 T’o fe Olugbala;

 Ni oso Re iyebiye,

 Awon ti O fe.

Bi irawo owuro, nwon ns’ ade Re loso,

 Ewa won o yo pupo, ewa f’ ade Re. Amin



Yoruba Hymn  APA 466 - Gbat’ O ba de, gbat’ O ba de

This is Yoruba Anglican hymns, APA 466- Gbat’ O ba de, gbat’ O ba de . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post