Yoruba Hymn APA 472 - Jehofa! Olorun ogo

Yoruba Hymn APA 472 - Jehofa! Olorun ogo

Yoruba Hymn  APA 472 - Jehofa! Olorun ogo

APP 472

 1. Jehofa! Olorun ogo,

 Je ki omode yin O;

 A wole n’ irele fun O,

 Ore Re ni orin wa.

 Ogun Seraf dapo gberin

 Ife Re l’ oke orun;

 Olorun ogo, gbo tiwa,

 B’ a tin yin oruko Re.


2. Emmanuel! Iwo t’ a bi,

 T’ a si fi ko or’ igi,

 O pe omode kekere,

 Lati wa si odo Re;

 Oluwa, ’b’ o ti pe, a de,

 Je k’ a ri anu Re gba!

 K’ awa, pel’ awon omo Re,

 K’ a sin O, k’ a si fe O.


3. A ba le wa, k’ a si fe O,

 K’ a si beru Re l’ aiye;

 Nikehin, k’ a wa pelu Re,

 K’ a ri O, k’ a si yin O.

 Jesu Olorun itunu,

 Olori ore! dide,

 Fi igbala Re bukun wa,

 Jo tewogba orin wa. Amin.



Yoruba Hymn  APA 472 - Jehofa! Olorun ogo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 472- Jehofa! Olorun ogo . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post