Yoruba Hymn APA 538 - Pase ’bukun Re t’oke wa

Yoruba Hymn APA 538 - Pase ’bukun Re t’oke wa

 Yoruba Hymn  APA 538 - Pase ’bukun Re t’oke wa

APA 538

1. Pase ’bukun Re t’oke wa,

 Olorun, s’ ara Ijo yi;

 Fi ife ti Baba wo wa,

 Gbat’ a f’ eru gboju soke.


2. Pase ibukun Re, Jesu,

 K’ a le se omo ehin Re;

 Soro ipa s’ okan gbogbo,

 So f’ alailera, tele mi.


3. Pase ’bukun l’ akoko yi,

 Emi oto, kun ibi yi;

 F’ agbara iwosan Re kun,

 At’ ore-ofe isoji. Amin.Yoruba Hymn  APA 538 - Pase ’bukun Re t’oke wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 538-  Pase ’bukun Re t’oke wa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post