Yoruba Hymn APA 554 - Niwaju ite Jehofa

Yoruba Hymn APA 554 - Niwaju ite Jehofa

Yoruba Hymn  APA 554 - Niwaju ite Jehofa

APA 554

 1. Niwaju ite Jehofa,

 E f’ayo sin, oril’ ede;

 Mo p’ Oluwa, on kanso ni,

 O le da, O si le parun.


2. Ipa Re, laisi ranwo wa,

 F’ amo da wa ni enia;

 Nigba t’a sako b’agutan,

 O tun wa mu si agbo Re.


3. A o f’ orin sunmo ’le Re,

 Lohun giga l’a o korin;

 Ile, l’ egbarun ahon re,

 Y’o f’ iyin kun agbala Re.


4. Ase Re gboro b’agbaiye,

 Ife Re po b’aiyeraiye;

 Oto Re y’o duro lailai,

 ’Gbat’ odun o dekun ’yipo. Amin.Yoruba Hymn  APA 554 - Niwaju ite Jehofa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 554-  Niwaju ite Jehofa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post