Yoruba Hymn APA 555 - N’nu gbogbo ayida aiye

Yoruba Hymn APA 555 - N’nu gbogbo ayida aiye

Yoruba Hymn  APA 555 - N’nu gbogbo ayida aiye

APA 555

 1. N’nu gbogbo ayida aiye,

 Ayo on wahala;

 Iyin Olorun ni y’o ma

 Wa l’enu mi titi.


2. Gbe Oluwa ga pelu mi,

 Ba mi gb’Oko Re ga;

 N’nu wahala, ’gba mo kepe,

 O si yo mi kuro.


3. Ogun Olorun wa yika

 Ibugbe oloto;

 Eniti o ba gbekele,

 Yio si ri ’gbala.


4. Sa dan ife Re wo lekan,

 Gbana ’wo o mo pe,

 Awon t’ o di oto Re mu

 Nikan l’ eni ’bukun.


5. E beru Re, enyin mimo,

 Eru miran ko si;

 Sa je ki ’sin Re j’ayo nyin,

 On y’o ma toju nyin. Amin.Yoruba Hymn  APA 555 - N’nu gbogbo ayida aiye

This is Yoruba Anglican hymns, APA 555-  N’nu gbogbo ayida aiye. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post