Yoruba Hymn APA 562 - A korin s’ Omo Olorun

Yoruba Hymn APA 562 - A korin s’ Omo Olorun

 Yoruba Hymn  APA 562 - A korin s’ Omo Olorun

APA 562

1. A korin s’ Omo Olorun,

 Odagutan t’a pa;

 Ti orun ati aiye mbo,

 T’O ye lati joba.


2. Si O l’ awon Angeli nke,

 L’ ekun gbogbo orun:

 “Mimo, mimo, mim’ Olorun,

 T’ ogo, at’ om’ ogun.”


3. Ijo Re li aiye dapo,

 Lati ma kepe O;

 Didan Olanla Olorun,

 T’ O l’ agbara gbogbo.


4. Larin won ni gbogbo wa nfe

 Lati yin eje Re;

 Joba l’ aiye ati l’ orun,

 ’Wo Omo Olorun. Amin. Yoruba Hymn  APA 562 - A korin s’ Omo Olorun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 562- A korin s’ Omo Olorun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post