Yoruba Hymn APA 565 - Alleluya! Orin t’o dun

Yoruba Hymn APA 565 - Alleluya! Orin t’o dun

Yoruba Hymn  APA 565 - Alleluya! Orin t’o dun

APA 565

 1. Alleluya! Orin t’o dun,

 Ohun ayo ti ki ku:

 Alleluia! Orin didun,

 T’ awon t’o wa lorun fe;

 N’le ti Olorun mi ngbe,

 Ni nwon nko tosantoru.


2. Alleluya! Ijo orun,

 E le korin ayo na.

 Alleluia! Orin ‘segun

 Ye awon t’a rapada

 Awa ero at’ alejo,

 Iyin wa ko nilari.


3. Alleluya! Orin ayo

 Ko ye wa nigbagbogbo.

 Alleluia! Ohun aro

 Da mo orin ayo wa;

 Gbat’ a wa laiye osi yi,

 A ni gbawe f’ ese wa.


4. Iyin dapo m’ adua wa;

 Gbo tiwa, Metalokan!

 Mu wa de ‘waju Re layo,

 K’a r’ Odaguntan t’a pa:

 K’a le ma ko Alleluya

 Nibe lai ati lailai. Amin.Yoruba Hymn  APA 565 - Alleluya! Orin t’o dun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 565-  Alleluya! Orin t’o dun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post