Yoruba Hymn APA 566 - Ji, okan mi, dide layo

Yoruba Hymn APA 566 - Ji, okan mi, dide layo

 Yoruba Hymn  APA 566 -  Ji, okan mi, dide layo

APA 566

1. Ji, okan mi, dide layo,

 Korin iyin Olugbala;

 Ola Re bere orin mi:

 ‘Seun nife Re ti po to!


2. O ri mo segbe n’ isubu,

 Sibe, O fe mi l’ afetan;

 O yo mi ninu osi mi:

 ‘Seun ‘fe Re tit obi to!


3. Ogun ota dide si mi,

 Aiye at’ Esu ndena mi,

 On nmu mi la gbogbo re ja;

 ‘Seun ‘fe Re ti n’ipa to!


4. ‘Gba ‘yonu de, b’ awosanma,

 T’o su dudu t’o nsan ara;

 O duro ti mi larin re:

 ‘Seun ‘fe Re ti dara to!


5. ‘Gbagbogbo l’okan ese mi

 Nfe ya lehin Oluwa mi;

 Sugbo bi mo ti ngbagbe Re,

 Iseun ife Re ki ye,


6. Mo fere f’aiye sile na,

 Mo fe bo low’ ara iku;

 A! k’ emi ‘kehin mi korin

 Iseun ife Re n’ iku.


7. Nje k info lo, ki nsi goke,

 S’ aiye imole titi lai;

 Ki nf’ ayo iyanu korin

 Iseun ife Re lorun. Amin.Yoruba Hymn  APA 566 -  Ji, okan mi, dide layo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 566-  Ji, okan mi, dide layo. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post