Yoruba Hymn APA 569 - Ise gbogbo ti awa nse

Yoruba Hymn APA 569 - Ise gbogbo ti awa nse

Yoruba Hymn  APA 569 - Ise gbogbo ti awa nse

APA 569

 1. Ise gbogbo ti awa nse,

 Ni Olorun ti ri;

 Ero gbogbo t’o wa ninu,

 Ni Olorun si mo.


2. A ko le f’ese wa pamo,

 Gbogbo won l’ O ti mo:

 A npuro, a ntan ’ra wa je,

 B’ a ro pe ko mo won.


3. Ohun gbogbo han ni gbangba,

 Ni oju Olorun;

 Okunkun ati imole,

 Si ri bakanna fun.


4. Olorun, je k’a ranti pe,

 Oju re si ri wa;

 Si je ki awa k’o beru

 Lati dese si O. Amin.Yoruba Hymn  APA 569 - Ise gbogbo ti awa nse

This is Yoruba Anglican hymns, APA 569- Ise gbogbo ti awa nse. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post