Yoruba Hymn APA 570 - Oluwa, Iwo wadi mi

Yoruba Hymn APA 570 - Oluwa, Iwo wadi mi

 Yoruba Hymn  APA 570 - Oluwa, Iwo wadi mi

APA 570

1. Oluwa, Iwo wadi mi,

 Em’ ise owo Re;

 Ijoko on idide mi,

 Ko pamo loju Re.


2. N’ ile mi, ati l’ona mi,

 N’ Iwo ti yi mi ka;

 Ko s’ iro tabi oro mi,

 T’ Iwo ko ti mo tan.


3. Niwaju ati lehin mi,

 N’ Iwo ti se mi mo;

 Iru ’mo yi se ’yanu ju,

 Ti emi ko le mo.


4. Lati sa kuro loju Re,

 Is’ asan ni fun mi,

 Emi Re lu aluja mi,

 Be ni mo sa lasan.


5. Bi mo sa sinu okunkun,

 Asan ni eyi je;

 Imole l’ okunkun fun O,

 B’ osangangan l’o ri.


6. Bi Iwo ti mo okan mi,

 Lati’ inu iya mi;

 Je ki emi k’o f’ ara mi

 Fun O Olugbala. Amin. Yoruba Hymn  APA 570 - Oluwa, Iwo wadi mi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 570-  Oluwa, Iwo wadi mi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post