Yoruba Hymn APA 573 - Baba wa, Olodumare

Yoruba Hymn APA 573 - Baba wa, Olodumare

 Yoruba Hymn  APA 573 - Baba wa, Olodumare

APA 573

1. Baba wa, Olodumare,

 ’Wo t’o kawo igbi omi,

 ’Wo t’o ti f’ ipo okun fun,

 Ti ko le re ibe koja;

 Gbo tiwa, gbat’ a nkepe O,

 F’ awon t’o wa loju omi.


2. Olugbala, ’wo t’oro Re

 Mu igbi omi pa roro,

 Iwo t’o rin l’ ori omi,

 T’o sun b’ enipe ko si nkan;

 Gbo tiwa, gbat’ a nkepe O

 F’ awon t’o wa loju omi.


3. Metalokan, Alagbara,

 Dabobo won ninu ewu;

 Lowo apata at’ iji,

 Lowo ina ati ota;

 Si je k’a ma korin ’yin Re,

 L’ or’ ile ati lor’ omi. Amin.Yoruba Hymn  APA 573 - Baba wa, Olodumare

This is Yoruba Anglican hymns, APA 573- Baba wa, Olodumare. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post