Yoruba Hymn APA 578 - Ife l’ Olorun, anu Re

Yoruba Hymn APA 578 - Ife l’ Olorun, anu Re

 Yoruba Hymn  APA 578 - Ife l’ Olorun, anu Re

APA 578

1. Ife l’ Olorun, anu Re

 Tan si ona wa gbogbo;

 O fun wa ni alafia,

 Ife ni Olorun wa.


2. Iku ndoro pupopupo,

 Enia si ndibaje;

 Sugbon anu Re wa titi,

 Ife ni Olorun wa.


3. Lakoko t’o dab’ o sokun,

 A nri ore Re daju;

 O tan imole Re fun wa,

 Ife ni Olorun wa.


4. O so ’reti, at’ itunu

 Mo aniyan aiye wa;

 Ogo Re ntan nibigbogbo,

 Ife ni Olorun wa. Amin. Yoruba Hymn  APA 578 - Ife l’ Olorun, anu Re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 578 -  Ife l’ Olorun, anu Re. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post