Yoruba Hymn APA 581 - Awa fe ohun aiye yi

Yoruba Hymn APA 581 - Awa fe ohun aiye yi

 Yoruba Hymn  APA 581 - Awa fe ohun aiye yi

APA 581

1. Awa fe ohun aiye yi,

 Nwon dara l’ oju wa;

 A fe k’a duro pe titi,

 Laifi won sile lo.


2. Nitori kini a nse be?

 Aiye kan wa loke;

 Nibe l’ ese on buburu

 Ati ewu ko si.


3. Aiye t’o wa loke orun,

 Awa iba je mo!

 Ayo, ife, inu rere,

 Gbogbo re wa nibe.


4. Iku, o wa ni aiye yi;

 Ko si loke orun;

 Enia Olorun wa mbe,

 Ni aye, ni aiku.


5. K’a ba ona ti Jesu lo,

 Eyi t’O la fun wa;

 Sibi rere, sibi ’simi,

 S’ ile Olorun wa. Amin. Yoruba Hymn  APA 581 - Awa fe ohun aiye yi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 581-  Awa fe ohun aiye yi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post