Yoruba Hymn APA 582 - Igba aro ati ayo

Yoruba Hymn APA 582 - Igba aro ati ayo

 Yoruba Hymn  APA 582 - Igba aro ati ayo

APA 582

1. Igba aro ati ayo

 Lowo Re ni o wa,

 Itunu mi t’owo Re wa,

 O si lo l’ase Re.


2. Bi O fe gba won lowo mi,

 Emi ki o binu;

 Ki emi ki o to ni won,

 Tire ni nwon ti se.


3. Emi ki y’o so buburu,

 B’ aiye tile fo lo;

 Emi o w’ ayo ailopin,

 Ni odo Re nikan.


4. Kil’ aiye ati ekun re?

 Adun kikoro ni;

 ’Gbati mo fe ja itanna,

 Mo b’ egun esusu.


5. Pipe ayo ko si nihin,

 Ororo da l’oyin:

 Larin gbogbo ayida yi,

 ’Wo ma se gbogbo mi. Amin.Yoruba Hymn  APA 582 - Igba aro ati ayo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 582-  Igba aro ati ayo. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post