Yoruba Hymn APA 586 - Ma koja mi, Olugbala

Yoruba Hymn APA 586 - Ma koja mi, Olugbala

Yoruba Hymn  APA 586 - Ma koja mi, Olugbala

APA 586

 1. Ma koja mi, Olugbala,

 Gbo adura mi;

 ’Gbat’ Iwo ba np’ elomiran,

 Mase koja mi!

 Jesu! Jesu! Gbo adura mi!

 Gbat’ Iwo ba np’ elomiran,

 Mase koja mi.


2. N’ ite-anu, je k’ emi ri

 Itura didun;

 Teduntedun ni mo wole,

 Jo ran mi lowo.

 Jesu! Jesu! &c.


3. N’ igbekele itoye Re,

 L’ em’ o w’ oju Re;

 Wo ’banuje okan mi san,

 F’ ife Re gba mi.

 Jesu ! Jesu ! &c.


4. ’Wo orisun itunu mi,

 Ju ’ye fun mi lo;

 Tani mo ni laiye lorun,

 Bikose Iwo?

 Jesu ! Jesu ! &c. Amin.Yoruba Hymn  APA 586 - Ma koja mi, Olugbala

This is Yoruba Anglican hymns, APA 586- Ma koja mi, Olugbala. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post