Yoruba Hymn APA 585 - Jesu, o ha le je be pe

Yoruba Hymn APA 585 - Jesu, o ha le je be pe

 Yoruba Hymn  APA 585 - Jesu, o ha le je be pe

APA 585

1. Jesu, o ha le je be pe,

 Ki eni kiku tiju Re?

 Tiju Re!-Wo t’ Angeli nyin,

 Ogo Eni nran titi lai!


2. Ki ntiju Jesu! O ya se

 Ki ale tiju irawo:

 On ni ntan imole orun

 Sinu okan okunkun mi.


3. Ki ntiju Jesu! Ore ni,

 Eni mo nwo lati d’ orun;

 Ewo: nigba mo ba ntiju,

 Kin ye bowo f’oko Re ko?


4. Ki ntiju Jesu! emi le,

 Bi nko l’ese lati wenu;

 Ti nko ni toro ire kan;

 Ti nko l’okan lati gbala.


5. Bi beko mo nhale lasan;

 Lasan ko l’Olugbala ku;

 A! k’eyi je isogo mi

 Pe, Jesu ko si tiju mi. Amin.Yoruba Hymn  APA 585 - Jesu, o ha le je be pe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 585-  Jesu, o ha le je be pe. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post